Ìgbà Kámbríà
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ìgbà Kámbríà (Cambrian) ni igba oniseorooriile akoko ti Àsíkò Ìgbéàtijọ́, to pari lati 542 ẹgbẹgbẹ̀rún ọdún sẹ́yìn dé 488.3 ẹgbẹgbẹ̀rún ọdún sẹ́yìn (ICS, 2004,[5] chart); Ìgbà Ọ̀rdòfísíà ni o tele. Ko si ojutu bo se pin si. Adam Sedgwick lo sedasile igba yi, o pe ni Cambria, oruko ede Latin fun Wales, nibi ti awon apata Britani Igba Kambria ti yojade daada.[6]

Ìgbà Kámbríà 542–488.3 ẹgbẹgbẹ̀rún ọdun sẹ́yìn | |
Mean atmospheric O2 content over period duration | ca. 12.5 Vol %[1] (63 % of modern level) |
Mean atmospheric CO2 content over period duration | ca. 4500 ppm[2] (16 times pre-industrial level) |
Mean surface temperature over period duration | ca. 21 °C[3] (7 °C above modern level) |
Sea level (above present day) | Rising steadily from 30m to 90m[4] |
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads