Ẹranko elégungun
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ẹranko elégungun /ˈvɜːrtəˌbrəts/ ni ó kó gbogbo ẹ̀yà ẹranko tí wọ́n jẹ́ lára ẹbí (subphylum) ẹranko elégungun ma ń sábà ní /ʔə/ chordates (egungun ẹ̀yìn). Ẹranko elégungun ni wọ́n jẹ́ púpọ̀ níní ẹbí phylumChordata, tí wọ́n tó ẹgbẹ̀rún lé láàdọ́rin àti ọgórùn ún ó dín méje (69,963) níye ẹ̀yà tí a gbọ́ nípa wọn.[4] Lála àwọn àkójọpọ̀ àwọn ẹranko elégungun ni:
- ẹja aláìnírùngbọ̀n
- Ní abẹ́ ẹ̀yà ẹranko elégungun onírùngbọ̀, ni a ti lè rí àwọn ẹranko bíi ẹjà cartilaginous (ẹja ṣáàkì, rays, àti ratfish)
- Ní abẹ́ ẹ̀yà ẹranko elégungun tetrapods,ni a ti lè rí amphibians, afàyàfà, ẹyẹ àti àwọn ẹranko afọ́mọlọ́mú gbogbo.
- ẹja eléegun púpọ̀[5] [6]
Remove ads
Àwọn Ìtọ́ka sí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads