Ẹ̀yà Ibibio
eya orile-ede Naijiria From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Àwọn Ibibio tabi Àwọn ọmọ Ibiobio jẹ́ àwọn ẹ̀yà kan tí ó wà ní apá Gúúsù Nàìjíríà.[6] Wọ́n wọ́pọ̀ ní ìpínlẹ̀ Akwa Ibom, Ìpinlẹ̀ Cross River àti ní ìlà oòrùn Ìpínlẹ̀ Abia.[7] Wọ́n tan mọ́ àwọn ẹ̀yà Efik.[8] Nígbà ìṣàkóso àwọn gẹ̀ẹ́sì ìjọba amúnisìn ní Nàìjíríà, àwọn Ibibio bèrè òmìnira lọ́wọ́ ìjọba Brítènì.
Àwọn Annang, Efik, Ekid, Oron àti Ibeno pín orúkọ, àṣà àti ìṣe kan pẹ̀lú àwọn ènìyàn Ibibio, èdè wọn sí jọra.[9] Àwọn ènìyàn Ekpo àti Ekpe wà lára ìṣèlú Ibibio.[10]
Remove ads
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads