Ọyẹ́

From Wikipedia, the free encyclopedia

Ọyẹ́
Remove ads

Ọyẹ́ jẹ́ àsìkò kan lápá ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà tí ó má a ń wáyé láàárín ìparí oṣù kọkànlá sí àárín oṣù kẹta ọdún. Ó jẹ́ àsìkò ẹrùn tàbí ọ̀gbẹlẹ̀ tí ó máa ń fa eruku.[1] Orúkọ náà farajọ ọ̀rọ̀ náà ọyẹ́, ní èdè Twi.[2] Ó má a ń jẹ́ àsìkò òtútù, ní àwọn àgbègbè mìíràn ẹ̀wẹ̀, ó máa ń jẹ́ àsìkò oru, èyí máa ń dá lórí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ojú ọjọ́ ní irú àgbègbè bẹ́ẹ̀.[3]

Thumb
Ọyẹ́ ní àyíká Abuja National Mosque in Abuja

Afẹ́fẹ́ Ọyẹ́ máa ń fẹ́ lásìkò ẹ̀rùn tàbí ọ̀gbẹlẹ̀, ní àsìkò tí ọ̀òrùn kì í fi bẹ́ẹ̀ ràn dáradára.

Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads