Abdullahi Sule

Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Abdullahi Sule (a bi ni ọjọ kẹ́rìndínlọ́gbọ̀n, Oṣu kejila, ọdun 1959) jẹ oniṣowo ati olóṣèlú Naijiria ti o jẹ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Nasarawa. Wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Nasarawa nínú ìdìbò Gómìnà ọdún 2019 lábẹ́ ètò ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressive Congress (APC).[1][2][3]

Quick facts Engineer Abdullahi Sule, Gómìnà ìpínlẹ̀ Nasarawa ...
Remove ads

Ìgbésí ayé rẹ

Wọ́n bí Sule ní Gudi, Akwanga ní ìpínlẹ̀ Nasarawa ní ọjọ́ kẹrindinlogbon oṣù Kejìlá ọdún 1959.[4] Ni ọdún 1968, Ó kẹ́kọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ Roman Catholic Mission (RMC) tí ó wà ní Gudi Station, ti o sí parí ilé-ẹ̀kọ́ gírámà ní Zang Secondary School ní ọdún 1974.[4]

Òṣèlú

Ni ọjọ kẹwà oṣù kẹta ọdún 2019, wón kede Adullahi Sule gẹgẹ bi gómìnà Ipínlè Nasarawa ti wón dibo yan.[5][6][2]

Àwọn itọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads