Abike Dabiri

Oníwé-Ìròyín From Wikipedia, the free encyclopedia

Abike Dabiri
Remove ads

Abike Kafayat Olúwa Toyin Dabiri-Erewa jẹ́ òṣèlú àti ọmọ ẹgbẹ́ tẹ́lẹ̀ fún Nigeria Federal House of Representatives, òun sì ni aṣojú fún Ìlú Ìkoròdú tí Ìpínlẹ̀ Èkó níbẹ̀.[1][2] Òun ni alága tẹ́lẹ̀ fun ìgbìmò ìkéde àti media.[3] Òun sì ní alága tẹ́lẹ̀ fún ìgbìmò Diaspora Affairs.[4] Ní ọdún 2015, ó di oluranlọwọ pàtàkì àgbà fún Olórí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari lórí ọ̀rọ̀ àjèjì. Ní oṣù kọkànlá ọdún 2018, ó di alákóso fún àwọn ọmọ Nàìjíríà tí ó wà ní Diaspora Commission.[5][6][7][8][9][10] Ó jẹ́ olùfọwọ́sí fún Together Nigeria, tí ó jẹ́ ètò tí wọn gbé kalẹ̀ láti lè si ṣẹ́ kí Buhari lé wọlé gẹ́gẹ́ bíi olórí orílẹ̀ èdè ni ọdún 2019.[11] O gboyè nínú èdè gẹ̀ẹ́sì ni ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Ifè. O lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Lagos níbi tí ó tí gboyè  masters nínú Mass Communication.[12]

Quick Facts Chairman/CEO of Nigerian Diaspora Commission, Àwọn àlàyé onítòhún ...
Remove ads

Iṣẹ́

Dabiri ṣi ṣé pẹ̀lú Nigerian Television Authority (NTA) fún ọdún mẹ́ẹ̀dógún, ó sì ṣe atọkun fún àwọn ètò ìròyìn pàápàá jù lọ ní pa ìṣẹ́. Ó fi ise agbóhùnsáfẹ́fẹ́ sílè fún òṣèlú. Òun ni alága fún ìgbìmò media ni Federal House of Representatives láti ọdún 2007.[2][13]

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads