Abo pẹ́pẹ́yẹ
iru ti eranko ti n gbé ni omi ati o le fo ni orun From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Abo pẹ́pẹ́yẹ (goose), awon abo pẹ́pẹ́yẹ le fo ni orun, won le fo pelu iyara ti mejidinlaadorun kilomita ni wakati okan (88km/w). [1] Awon pẹ́pẹ́yẹ n gbé ni omi ikudu, adagun, irà, igbe, ati léti ile-iwé, koriko, ati léti omi. Omi fun abo si won, abo lati awon eranko ti fe je won bi ounje.[2]Abo


Abo Pẹ́pẹ́yẹ Afirika
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads
