Achmatowicz reaction
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Achmatowicz Reaction jẹ́ ìṣètò organic èyí tí furan ma a ń yípadà sí dihydropyran. Ní àtẹ̀jáde Osman Achmatowicz Jr. àkọ́kọ́ ní ọdún 1971 [1] furfuryl alcohol dàpapọ̀ ṣiṣẹ́ pẹ̀lú bromine ní methanol sí 2,5-dimethoxy-2,5-dihydrofuran tí ó tún ara ṣàjọ sí dihydropyran pẹ̀lú àdàpọ̀ sulfuric acid. Àwọn ìgbésẹ̀ ìdàpapọ̀ ṣiṣẹ́ míràn, ìdáàbòbò alcohol pẹ̀lú methyl orthoformate àti boron trifluoride) àti ìmúkù ketone pẹ̀lú sodium borohydride ṣe ìmújáde èyí tí a lè ṣètò monosaccharides lati inú rẹ̀.
Wọ́n ti lo ìlànà Achmatowitz lati ṣètò àwọn molecule tó lágbára fún àpẹẹrẹ bí tidesoxoprosophylline,[2] Pyrenophorin [3] àti Bao Gong Teng A.[4] Láìpẹ́ yìí wọ́n lòó fún ìmú ìlọsíwájú bá ìṣètò kẹ́míkà.[5][6]
Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads