Adebayo Salami
Olóṣèlú Naijiria From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Adébáyọ̀ Sàlámì tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Ọ̀gá Bello (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ Kẹ̀sán-án oṣù karùn-ún ọdún 1953) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ ìpínlẹ̀ Kwara lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1][2]

![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads