Adesewa Josh

Akọ̀ròyìn ní Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Adesewa Hannah Ogunleyimu , tí wọ́n bí ní ọjọ kọkànlá oṣù kẹwa , ọdún 1985. Adesewa Josh, jẹ akoroyin orilẹ - èdè Nàìjíríà tí ó n kọ iroyin tilé toko fúnTRT World. [1] Nigba kan ri, ó jé oṣiṣẹ ni ilé-isẹ́ telifisan Channels TV lati ọdún 2012 sí ọdún 2017.[2]

Quick facts Ọjọ́ìbí, Ẹ̀kọ́ ...
Remove ads

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

Josh ní wọn bí ní àdúgbò Ipetu-Ijesha ní ìlúOsun State ní apá ìwọòrùn Nàìjíríà sí ilé Josiah Ogunleyimu, bàbá rẹ,tí ó wá láti ìlú Osun ní orilẹ-ede Nàìjíríà àti Abimbola Ogunleyimu, ìyá rẹ tí ó wá láti agbègbè Epe, ni ilú Èkó.

Ní ọdún 2009, Josh gbà a ìwé èrí nínú igberoyin jáde àti ìjábọ̀ lọ́wọ́ BBC World Service.[2] Ní ọdún 2010, ó gba iwe-eri nínú ìjọba lọwọ ilé-isẹ́ Alder ati ni ọdún 2012, o tun gba iweeri nínú ìmọ bí a se n gbe eto jade lori ẹrọ amóunmáwòrán ni UK's Aspire Presenting Institute.[2] Ó tún ní iwe-eri nínú ìfáàrà ètò ìroyin lọwọ Redio Nàìjíríà.[3]

Remove ads

Isẹ́

Ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ọdún 1990, Josh sisẹ́ gẹgẹ bi osere ọmọde l'orilẹ ede Nàìjíríà , níbi tí o ti jẹyọ ní ABC Wonderland from Galaxy Television. O tun ṣiṣẹ lórí ọsẹ ti orukọ rẹ n jẹTinsel. Josh tun jẹyọ ní University of Ibadan Theater Art Hall fun ìgbéjáde tíátà níbí tí o ti jẹyọ ninu Wedlock of the Gods, The Gods are Not to Blame, àti Under the Moon.

Ni ọdun 2007, Josh wà lára àwọn ẹgbẹ amóunmáwòrán orilẹ-ede Nàìjíríà tí wón se ètò tí wón pe ní Next Movie Star, tí o da lórí ṣíṣe àwárí awọn tí o ni ẹ̀bùn nínú eré ṣíṣe.

Ní ọdún 2012, Josh ṣe ètò amóunmáwòrán kan ti a pè nì Lucozade Boost Freestyle pẹlu Julius Agwu. O tun jẹyọ gẹgẹ bí adajọ lórí Nigerian Idol.

Ni oṣu keje ọdún 2012, Josh bẹrẹ iṣẹ rẹ gẹgẹ bi akọroyin gẹgẹ bi igbakeji ètò arọ ti a mọ sì Sunrise Daily lórí Nigerian cable news network Channels TVLagos, Nigeria. O di akaroyin irọlẹ fún Channels TV ti o si ṣiṣe gẹgẹ bí ajabọ ìròyìn ti ṣi gba ipo di ọdún 2017.[2][4]

Remove ads

Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

  • 2016: CHAMP Xceptional Women Network, Xceptional Women in Media Award[5][6]
  • 2017: The Future Awards Africa, The Future Awards Prize for On-Air Personality (Visual), Nominee[7]

Àwọn ẹgbẹ́ tó darapọ̀ mọ́

  • 2016: Junior Achievement Nigeria
  • 2016: Nigerian Leadership Initiative, Associate Fellow
  • Young African Leaders Initiative, YALI Network Member
  • Global Investigative Journalism Network (GIJ)

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads