Adetokunbo Ademola
Onigbejo naijiriya From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Adetokunbo Adegboyega Ademola, KBE, GCON (1 February 1906 - 29 January 1993) jẹ́ adájọ́ àgbà ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ adájọ́ àgbà ile Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ rí , àti ọmọ Ọba Ladapo Ademola II, tí ó jẹ́ Aláké ti Ẹ̀gbá tẹ́lẹ̀.[1] [2]
Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads