Adil Abdul Mahdi

From Wikipedia, the free encyclopedia

Adil Abdul Mahdi
Remove ads

Adil (Adel) Abdul-Mahdi (al Muntafiki) (Lárúbáwá: عادل عبد المهدى ) (ojoibi 1942 ni Baghdad, Iraq) je Shi'a oloselu, onimo oro-okowo ati ikan ninu awon Igbakeji Aare ile Irak meji tele. Teletele o ti je Alakoso Eto Inawo ninu ijoba igbadie.

Quick Facts Prime Minister of Iraq, Ààrẹ ...
Remove ads

Ìgbẹ́ ayé rẹ̀

Wọ́n bí Adil ní ìlú Baghdad ní ọdún 1942. Ó kẹ́kọ́ ní Baghdad College. Ó kẹ́kọ́ nípa ìmọ̀ Economics ní fasiti Baghdad. Adil ṣiṣẹ́ gẹgẹ bí akọ̀wé fun Iraqi foreign Ministry ni ọdún 1965. Ni ọdún 1972, o keko gboye Masters ni fasiti University of Poitiers.

Ikọwe fiposile

Ni ojo kokandinlogbon, oṣù kọkànlá ọdún 2019, leyin ọpọlọpọ ifehonuhan, Mahdi sọpé ohun kowe fiposilẹ.[5][6] Aṣòfin Iraqi fọwọ́sí ikowe fiposilẹ rẹ ni ọjọ́ kinni, oṣù Kejìlá ọdún, 2019.


Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads