Ajawa language

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Ede Ajawa jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè Afro àti Asia tí ó ti parun tí wọ́n ń sọ ní Ìpínlẹ̀ Bauchi ní Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Èdè Ajawa jẹ́ òun ìgbàgbé láàrín ọdún 1920 sì ọdún 1940 látàri pé àwọn Olùsọ èdè náà bẹ̀rẹ̀ sí sọ èdè Haúsá.[1][2]

Quick facts Sísọ ní, Agbègbè ...
Remove ads

Àwọn Àkọsílẹ̀

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads