Ajiona Alexus
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ajiona Alexus Brown [1] (tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹta, ọdún 1996) jẹ́ òṣèrébìrin Orílẹ̀ èdè America tó di ìlúmọ̀ọ́ká látàrí ìfarahàn rè nínú eré The Rickey Smiley, Empire, 13 Reasons Why, Acrimony, and Breaking In. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ yìí ní ọdún 2008, nígbà tó pé ọmọdún méjìlá.[2][3][4]
Remove ads
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
Wọ́n bí Alexus ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹta, ọdún 1996, sí Tuskegee, ní Alabama. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní Alabama School of Fine Arts, níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa eré orí-ìtàgé.
Iṣẹ́ rè
Ní ọdún 2021, ó farahàn nínú eré Starz, pẹ̀lú Russell Hornsby, Da'Vinchi, Demetrius Flenory Jr., Eric Kofi-Abrefa, àti Michole Briana White.[5]
Àtòjọ àwọn fíìmù rè
Fíìmù àgbéléwò
Orí ẹ̀rọ-amóhùn-máwòrán
Àtòjọ orin rẹ̀
Mixtapes
Orin àdákọ
Promotional singles
Àwọn fọ́nrán orin
Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads