Alan Turing

From Wikipedia, the free encyclopedia

Alan Turing
Remove ads

Alan Mathison Turing, OBE, FRS (play /ˈtjʊərɪŋ/ TEWR-ing; 23 June 1912 – 7 June 1954), je ara Ilegeesi onimomathimatiki, onimo ogbon, aseatuwoipamo ati asesayensi komputa. O ko ipa pataki ninu idagbasoke sayensi komputa, nipa pipese isodimudaju awon itumo "algoritmu" ati "isiropo" ("computation") pelu ero Turin, to kopa pataki ninu idasile komputa odeoni.[1] Turing je gbigba bi baba sayensi komputa ati laakaye afowoda.[2]

Quick facts Ìbí, Aláìsí ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads