Àlgéríà (Arabiki: الجزائر, al-Gazā’ir), fun onibise Orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú àwọn Ènìyàn ilẹ̀ Àlgéríà, je orile-ede ni Àríwá Áfríkà. Ile re ni ti orile-ede ti o tobijulo ni Okun Mediterraneani, ekeji totobijulo ni orile Áfríkà[10] leyin Sudan, ati ikokanla totobijulo lagbaye.[11]
Quick facts Orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú àwọn Ènìyàn ilẹ̀ ÀlgéríàPeople's Democratic Republic of Algeria الجمهورية الجزائرية الديمقراطية الشعبية (Arabic)République algérienne démocratique et populaire (Faransé), Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ ...
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú àwọn Ènìyàn ilẹ̀ Àlgéríà People's Democratic Republic of Algeria
الجمهورية الجزائرية الديمقراطية الشعبية(Arabic) République algérienne démocratique et populaire(Faransé)
Àlgéríà i bode ni ariwailaorun mo pelu Tùnísíà, ni ilaorun pelu Libya, ni iwoorun pelu Moroko, ni guusuiwoorun pelu Apaiwoorun Sahara, Mauritania, ati Mali, ni guusuilaorun pelu Niger, ati ni ariwa pelu Okun Mediterraneani Sea. Titobi re fe je 2,400,000 square kilometres (930,000sqmi), be si ni iye awon eniyan re je 35,700,000 ni January 2010.[12] The capital of Algeria is Algiers.