Ìṣọ̀kan Áfríkà
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ìṣọ̀kan Áfríkà (Gígékúrú bí AU ní èdè Gẹ̀ẹ́sì tàbí UA jẹ́ ẹgbẹ́ ìṣọ̀kan tó ní àwọn Orílẹ̀-èdè Olómìnira Adúláwọ̀ márùnléláàádọ́ta (55) bí ọmọ ẹgbẹ́.[Morocco]] nìkan ni orílẹ̀-èdè Olómìnira tí kìí ṣe ọmọ ẹgbẹ́ àjọ Ìṣọ̀kan Adúláwọ̀ . Ìṣọ̀kan Afrikà jẹ́ dídásílẹ̀ ní ọjọ́ Kẹsàn án oṣù Keje, ọdún 2002 (9-7-2002),[8] Àjọ (AU) ni ó kalẹ̀ sí ìlú Addis Ababa, ní orílẹ̀-èdè Ethiopia.
Remove ads
Àwọn ọmọ ẹgbẹ́
Àwọn orílẹ̀-èdè ìsàlẹ̀ wọ̀nyí ni ọmọ ẹgbẹ́ Ìṣọ̀kan Áfríkà:[9]
![]() ![]() ![]() ![]() ![]() ![]() |
![]() ![]() |
Àdàkọ:RWA Àdàkọ:SADR Àdàkọ:STP Àdàkọ:SEN Àdàkọ:SEY Àdàkọ:SLE ![]() ![]() Àdàkọ:SSD[10] Àdàkọ:SUD ![]() ![]() ![]() ![]() Àdàkọ:UGA Àdàkọ:ZAM Àdàkọ:ZIM |
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Àwọn Ìtọ́ka sí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads