Òṣéré orí ìtàgé From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ali Nuhu Mohammed (táabì ni ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù kẹta, ọdún 1974) jẹ́ òṣèré ará Nàìjíríà àti olùdarí.[1]Ó má ń ṣe ère Haúsá àti ère Gẹ̀ẹ́sì. Àwọn òní ròyìn má ń pè ní "king of kannywood" tàbí "sarki". Kannywood ni orúkọ ilé ìṣe fímù Hausa.[2] Nuhu ti kópa nínú àwọn ère Nollywood Àti Kannywood tí ó tó Ẹ̀dẹ́gbẹ́ta filmu. [3]