Orílẹ̀-èdè kan ni ó ń jẹ́ American Samoa. Ètò ìkànìyàn 1995 sọ pé àwọn ènìyàn ibè jẹ́ ẹgbẹ̀rún lọ́nà ojójì ó lé mẹ́ta (43, 000). Èdè Gèésì ni èdè tí wọ́n fi ń ṣe ìjọba. Ìdá àádọ́rùn-ún nínú ọgọ́rùn-ún àwọn ènìyàn tí ó ń gbé ibẹ̀ ni ó ń sọ Samoan. Àwọn kan tún ń sọ Tongan àti Tokelau
Quick Facts American Samoa Amerika Sāmoa / Sāmoa Amelika, Olùìlú ...