Angas languages
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads

Èdè Angas, Angas–Sura,[1] or Central West Chadic languages[2] (tí wọ́n ń pè ní A.3 láti ìwọ oòrùn Chad) jẹ́ ọ̀kan lára èdè Ìwọ oòrùn Chad tí wọ́n ń sọ ní Ìpínlẹ̀ Plateau ni Ariwa Gúúsù ní orílè èdè Nàìjíríà
Remove ads
Àwọn Èdè
Èdè Angas ni :[3]
- Angas
- Ngasic: Ngas (Angas), Belnəng; ?Miler
- Mwaghavulic: Mwaghavul, Mupun (Mapun), Takas (Toos); Cakfem-Mushere
- Miship (Chip)
- Pan cluster
- Chakato; Jorto (spurious)
- Jipal, Mernyang (Mirriam), Kwagallak, Kofyar (Doemak), Bwol, Goram, Jibyal
- Nteng
- Tel (Tɛɛl, Montol)
- Talic: Tal, Pyapun, Koenoem
- Goemaic: Goemai
- Yiwom (Ywom, Gerka)[3]
Àkíyèsí wá pé nínú àwọn orúkọ èdè yìí, Àkọtọ́ wá fún oe tí ó dúró fún mid central vowel ə, èyí tó jẹ́ pé lọ́dọ̀ àwọn onísìn ni Alàgbà E. Sirlingerni agbègbè Shendam ni ọdún 1930 ni wọ́n ṣe Àkọtọ́ bẹẹ̀.[3][4][5]
Èdè Angas yàtọ̀ sí àwọn èdè tí ó wà ní ìwọ̀ oòrùn Chad nítorí kò ní Ẹ̀ka èdè tàbí mofọ́lọ́jì tí ó nira.[6]
Onírúurú ni Ede Ywom Ywom jẹ́.[7]
Remove ads
Fonọ́lọ́jì
Àwọn àbùdá fonọ́lọ́jì tí ó jọ mọ Èdè Chad ni àwọn ohun wọ̀nyí:[3]
- Palatalised consonants
- Implosive consonants ɓ, ɗ
- àwọn Fáwẹ́lì i, ɨ, u, ɛ, ɔ, a
- ìró ohun mẹ́ta
Orúkọ àti àwọn Àgbègbè
Ní ìsàlẹ̀ ni àtòpò àwọn Orúkọ Èdè Angas, eye àti àgbègbè tí a ti lè bá wọn pàdé gẹ́gẹ́ bí Blench (2019) tí sọ.[8]
Remove ads
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads