Ankara

From Wikipedia, the free encyclopedia

Ankara
Remove ads

Ankara ni oluilu ile Turki ati ilu titobijulo keji nibe leyin Istanbul. Ilu yi ni igasoke 938 metres (3,077 ft)[2], be sini ni 2007 iye awon eniyan ibe to 4,751,360, lapapo mo awon agbegbe mejo ti won wa labe imojuto ilu na.[1] Ankara tun je oluilu Agbegbe Ankara.

Quick facts Country, Region ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads