Anti-histone antibodies

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Anti-histone antibodies jẹ́ àwọn èròjà ìdáàbòbò ara tí ara má ń ṣètò rẹ̀ tí wọ́n sì maa ń ri ní ìdá àádọ́ta (50%) sí ìdá àádọ́rin (70%) àwọn aláìsàn tí wọ́n ní àrùn systemic lupus erythematosus (SLE) àti àwọn tí ó ju  95%  àwọn aláìsàn tí wọ́n ní àrùn drug-induced lupus erythematosus.[1]

ELISA tí wọ́n fi ń ṣe ìwádí anti-histone antibodies maa sọọ́ di mímọ̀ wípé ó wà lára tí ó bá rí ju 25 units/ml anti-histone antibodies nínú ẹ̀jẹ̀.[2]

Remove ads

Àwọn ìtọ́ka sí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads