Arthur Wellesley, 1st Duke of Wellington

From Wikipedia, the free encyclopedia

Arthur Wellesley, 1st Duke of Wellington
Remove ads

Arthur Wellesley, 1st Duke of Wellington, Field Marshal KG, KP, GCB, GCH, PC, FRS (c. 29 April/1 May 1769 – 14 September 1852), je omo Ilegeesi Irelandi[1] jagunjagun ati agbaalu, ati ikan larin awon asiwaju eniyan ologun ati oloselu orundun kandinlogun. O je titokasi bi "The Duke of Wellington" lasan, paapaa leyin iku re, nigbati awon Dukes of Wellington miran na ti joye. O tun di Alakoso Agba orile-ede Britani tele.

Quick facts Prime Minister of the United Kingdom, Monarch ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads