Ata rodo
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ata rodo (Látìnì: Capsicum chinense) jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ewébẹ̀ tí ó ṣe pàtàkì nínú ohun èlò ìsebẹ̀ jákè-jádò orílẹ̀ àgbáyé. Oríṣiríṣi ata rodo ni ó wà ní wà pàá pàá jùlọ ní àwọn ọjà ilẹ̀ Nàìjíríà. [1]

Ànfàní ata rodo
Ata rodo ni ó ní àwọn èròjà aṣara lóore Fítàmì bii : (C, A, B6 àti folate), ó tún ní èròjà (lycopeine àti capsaicin). Àwọn èròjà yí ni wọ́n wúlò fún mímu ìrora kúrò fúni, tí ó sì ma ń jẹ́ kí kẹ̀lẹ̀bẹ̀ ó dúrò ní ihò tàbí káà imú àti káà ọ̀fun. Ata rodo tun ń ṣèkúnlápá fún àwọn ọmọ ogun ara kí wọ́n lè lagbara si. Ti ta ata rodo ni ó tun ma ń jẹ́ kí ẹ̀fọ́rí oun kàtá ó fi àgbàọ́ ara sílẹ̀, kódà tó fi mọ́ àìsàn arọmọléegun, àti àwọn àìsàn mìíràn. [2]
Remove ads
Bí wọ́n ṣe ń jata rodo
Ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ko fi bẹ́ẹ̀ sí ónjẹ kan tí a lè sè láì sí ata rodo.[3]A lè lọ̀ọ́ mọ́ àwọn èròjà ọbẹ̀ tókù, a lè lọ̀ó lásán kí á fi ṣe kurumbúsú, a lè jẹ́ lásán a sì lè fi se ohun k lohun tó bá wùwá. [4]
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads