Ata ṣọ̀mbọ̀
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ata ṣọ̀mbọ̀ tàbí (chili) [1].[2] Ata ṣọ̀mbọ̀ ni wọ́n ma ń lo láti lè jẹ́ kí ónjẹ ó ta lẹ́nu. Èròjà (Capsaicin) ni ó ma ń fún ata ṣọ̀mbọ̀ ní agbára láti ṣe iṣẹ́ títa lẹ́nu.


Ibi tí ṣọ̀mbọ̀ ti ṣẹ̀ wà
Ata ṣọ̀mbọ̀ lò ni ó ṣẹ̀ wá láti orílẹ̀-èdè Mẹ́síkò [3]. Ata ṣọ̀mbọ̀ lò tan kalẹ̀ àgbáyé láti ilẹ̀ Mẹ́síkò látàrí ìdòwòpọ̀. Wọ́n máa ń lò ó fún oúnjẹ sísè àti òògùn ìbílẹ̀.
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads