Atlantic slave trade
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ìsòwò Ẹrú ní Atlantic tàbí transatlantic slave trade jẹ́ ìgbà tí àwọn oníṣòwò ẹrú bá gbé àwọn èèyàn aláwọ̀ dúdú kúrò gẹ́gẹ́ bí ẹrú láti orílé Áfíríkà lọsí Amẹ́ríkà. Àwọn ará Yúróòpù wọn á máa lo ọkọ̀ ojú omi, ẹrú tí wọ́n fi ń ṣe òwò ẹrú máa ń lo ọ̀nà ìṣòwò onígun mẹ́ta àti Arin Àárín inú Atlantic déédéé, ó sì wà láti ọ̀rúndún kẹrìndínlógún sí Ṣẹ́ńtúrì kọkàndíńlógún.[1]Púpọ́ júlọ nínú àwọn tí wọ́n gbé lọ fún ìṣòwò ẹrù nipasẹ̀ transatlantic jẹ́ àwọn ènìyàn láti àárín Africa àti Ìwọ̀-oòrùn Africa tí Àwọn onísòwò ẹrú tí Ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà tí tà sí àwọn oníṣòwò ẹrú bíi àwọn Portuguese, British, Spanish, Dutch, ati Faranse tí àwọn náà ń tá ẹrù.[2][3][4] nígbà tí àwọn míìràn tí wọn mú tààrà nípasẹ àwọn oníṣòwò ẹrú ní àwọn ibi ogun létí òkun


;[5] Àwọn oníṣòwò ẹrú ní ilẹ̀ Yúróòpù kóra jọ, wọ́n sì fi àwọn tí wọ́n wà lẹ́rú sẹ́wọ̀n láwọn ibi olódi ní etíkun Áfíríkà, wọ́n sì kó wọn wá sí ilẹ̀ Amẹ́ríkà.[6][7]Àyàfi Àwọn arà ìlu Portugal, àwọn oníṣòwò ẹrú Yúrópù ní gbogbogbò kò kópa nínú àwọn ikọlù nítori ìrètí ayé fún àwọn ará ìlù Yúrópù tí wọ́n wà ní ni ihà ìsàlẹ̀ aṣálẹ Sahara, èyí wáyé láárin ọdún kan láàárin àkókò tí ìṣòwò ẹrù (èyítí ó jẹ́ ìṣààjúu ní gbá tí ààrùn ibà wà ní jákèjádò tí wọn sí fí quinine ṣe ìtọjú iba náà.[3]Àwọn Orílẹ̀-èdè tí wọ́n wà ní apá Gúsù Atlantic ati ìletò Carribbean gbáralẹ́ àwọn Ẹrú fún ẹ̀tọ̀ ọrọ-aje wọ́n àti àwọn iṣé oríṣiríṣi èyí tí iṣé Ìrèké àti àwọn ohùn ọ̀gbìn mìíràn náà wà níbẹ̀. Èyí ní àwọn ará ilè Ìwo oòrùn Yórùpù wó pé ó jẹ́ òhun pàtàkì ti won sì ń bá àwọn orílé èdè miiran ní òpin 17th àti 18th Sẹ́ńtúrì, tí wọ́n ń bá ará wọn jà latiy sẹ̀dá Ìjọba tí ó ga júlo lórí àwọn ilù òkèrè (Colonial Empire).[8]
Remove ads
Ìpìlẹ Abẹ́lẹ̀
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads
