Austrálíà

From Wikipedia, the free encyclopedia

Austrálíà
Remove ads

Austrálíà (o-STRAYL-yə,[4] or /ɔːˈstreɪliə/ aw-STRAY-lee-ə), fun ibise bi Orílẹ̀-èdè Àjọni ilẹ̀ Austrálíà, je orile-ede ni Southern Hemisphere to ni gbogbo ile orile Ostralia (to kere julo laye),[5][6] erekusu Tasmania, ati opolopo awon erekusu kekeke ni inu okun India ati Pasifiki.N4 Awon orile-ede to ni bode pelu ni Indonesia, East Timor, ati Papua New Guinea ni ariwa, Solomon Islands, Vanuatu, ati New Caledonia ni ariwa-ilaorun, ati New Zealand ni guusuilaorun.

Quick Facts Orílẹ̀-èdè Àjọni ilẹ̀ Austrálíà Commonwealth of Australia, Olùìlú ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads