Fanuatu
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Vanuatu ( /ˌvɑːnuːˈɑːtuː/ (ìrànwọ́·info) vah-noo-AH-too or /ˌvænˈwɑːtuː/ van-WAH-too), ni onibise bi orile-ede Olominira ile Vanuatu (Faranse: République de Vanuatu, Bislama: Ripablik blong Vanuatu), je orile-ede erekusu to budo si Guusu Okun Pasifik. Ile arkipelago, to wa lati ileru, je bi 1,750 kilometres (1,090 mi) si ilaorun apaariwa Ostrelia, 500 kilometres (310 mi) si ariwailaorun Kaledonia Tuntun, iwoorun Fiji, ati guusuilaorun awon Erekusu Solomoni, leba Guinea Tutun.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads