Awka

From Wikipedia, the free encyclopedia

Awka
Remove ads

Awka (Igbo: Ọka)[1] ní olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Anambra, Nàìjíríà. Wọ́n sọ ìlú náà di olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Anambra ní 21 August 1991, nígbà tí wón ya Ìpínlẹ̀ Anambra kúrò lára Ìpínlẹ̀ Enugu. Gẹ́gẹ́ bí abayori ìkànìyàn ọdún 2006 ní Nàìjíríà, àwọn olùgbé Akwa tó 301,657. Ìpínlẹ̀ Awka wà láàrin Onitsha àti Enugu.

Quick facts Country, Ipinle ...

6°12′25″N 7°04′04″E

Remove ads

Àwọn Ìtókasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads