Awori
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Awori jẹ́ orúkọ Ìdílé, lára àwọn tí orúkọ ìdílé wọn jẹ Àwórì ni àwọn wọ̀nyí :
- W.W.W. Awori (1925–1978), àgbà nínú isẹ́ ìròyìn, Asọ̀fin, oníjà Òmìnira láti ìlú Keny.
- Aggrey Awori (1939–2021), Omínọ̀ nípa ọ̀rọ̀ ajé àti Òṣèlú orílẹ̀ èdè Uganda.
- Grace Awori, àbúrò sí Aggrey àti Moody, ìyá fún Susan àti Judi Wakhungu.
- Jeremy Awori (tí wọ́n bí ní ọdún 1971), jẹ́ oníṣòwò ìlú Kenya
- Maria Awori (tí wọ́n bí ní ọdún 1984), jẹ́ Olùwẹ̀ láti ìlú Kenya.
- Moody Awori (tí ọjọ́ ìbí rẹ̀ jẹ́ ọdún 1927), òṣèlú láti ìlú Kenya
- Wyllis Awori (tí wọ́n bí ní ọdún 2004), eléré rugby
U21 láti ìlú Kenya
Remove ads
E tún lè wo
- Ẹ̀yà Awori , àwọn ẹ̀yà kan nílé Yorùbá
Àdàkọ:Authority control
Àdàkọ:Surname
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads