Bakitéríà

From Wikipedia, the free encyclopedia

Bakitéríà
Remove ads

Baktéríà (en-us-bacteria.ogg [bækˈtɪərɪə] ; ìkan: Bakterio) je idipo ninla awon ohun elemintintinni prokarioti ti won ni ahamo eyokan. Gigun won je mitatintinni, idasi bakteria je orisirisi, lati roboto de opa de ilo. Bakteria wa nibi gbogbo ni ile-aye, won wu ninu erupe, omi kikan gbigbona, idoti[2],omi, ati jinjin ninu ile aye, bakanna ninu elo elemin, ati ninu ara awon ogbin ati eranko. 40 legbegberun ahamo bakteria ninu erupe gramu kan be sini egbegberun kan ahamo bakteria lo wa ninu omi; lapapo egbegberunkesan marun (5×1030) bakteria lowa ni aye[3] ti won sedajo opo isupoalaaye ni agbaye.

Quick Facts Baktéríà Temporal range: Archean or earlier - Recent, Ìṣètò onísáyẹ́nsì ...



Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads