Benedict Ayade
Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Benedict Ayade (bíi ní ọjọ́ kejì oṣù kẹta ọdún 1968) jẹ́ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Cross River tí wọ́n dìbò yàn wọlé ní Ọjọ́ ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n oṣù karún ọdún 2015, lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party, PDP.[1] Kí ó tó di gómìnà, ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà.[2]
Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads