Benjamin Akande

From Wikipedia, the free encyclopedia

Benjamin Akande
Remove ads

Benjamin Ola Akande jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America, tó sì tún jẹ́ onímọ̀, ọ̀jọ̀gbọ́n àti oníṣòwò ńlá. Ní oṣù May, ọdún 2021, wọ́n fi sípò ìgbá-kejì ààrẹ, Senior Vice President Chief Corporate Responsibility Officer (CCRO), Stifel Financial, èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìfowópamọ́ tó ń rí sí ìdókòwò. Òun ni ààrẹ kọkànlélógún ti Westminster College ní Fulton, Missouri.[1][2][3]

Quick Facts Senior Vice President Chief Corporate Responsibility Officer (CCRO), Stifel Financial ...
Remove ads

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads