Berom language

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Berom tàbí Birom (Cèn Bèrom) jẹ́ èdè tí ó àwọn ènìyàn ń sọ julọ nínú àwọn èdè PlateauNàìjíríà. Èdè Berom jẹ́ èdè tí ó wọ́pọ̀ láàrin àwọn ènìyàn Berom ní ìgbèríko. Ṣùgbọ́n, àwọn ènìyàn Berom ní ìlú ńlá ti ń sọ èdè Hausa.[1] Àwọn ènìyàn tí ó tó mílíọ̀nù kan (ní ọdún 2010) ni ó ń sọ èdè náà.[1]

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads