Bill Gates

From Wikipedia, the free encyclopedia

Bill Gates
Remove ads

William Henry "Bill" Gates III tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1955 (28th/10/1955)[2] jẹ́ oníṣòwò ọmọ orílẹ̀-èdè Amerika, alaanu, oludako ati alaga[3] ilé-iṣẹ́ Microsoft, ilé-iṣẹ́ atolànà kọ̀m̀pútà tó dá sílẹ̀ pẹ̀lú Paul Allen. Gates jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tó lọ́wọ́ jùlọ lágbàáyé[4] òun sì ni olówó jùlọ ní àgbáyé lọ́dún 1995, 2009, àyàfi ọdún 2008, nígbà tó bọ́ sí ipò kẹta.[5] Nígbà tó fi ṣíṣe ní Microsoft, Gates wà ní ipò CEO àti amójútó àgbà atolànà kọ̀m̀pútà, bẹ́ẹ̀ sì ni òun ni onípìn-ín ìdákowò tó tóbi jù lọ, ipin ajoni.[6] Ó tún ti kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé.

Quick facts Ọjọ́ìbí, Ibùgbé ...


Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads