Bindo Jibrilla
Oloselu Naijiria From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Bindo Jibrilla jẹ́ oníṣòwò, olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àárín Adamawa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà.[1] Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti Ọdún 2011 sí Ọdún 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Labour Party.[2]
Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads