Bode George

Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Olabode Ibiyinka George je agba oloselu omo bibi ipinle Eko ni apa iwo-oorun orile-ede Naijiria. A bii ni ojo kokanlelogun, osu kokanla odun 1945[1]. O ti figba kan je Gomina ijoba ologun Ipinle Ondo ni odun 1988 si 1990[2]. Titi di asiko yii, Bode George je omo egbe-oselu alatako People Democratic Party[3]

Quick Facts Olabode Ibiyinka George, 9th Governor of Ondo State ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads