Bode Thomas

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Oloye Bode Thomas (ti a bi ni ojo ketalelogun osu kokanla odun 1919 ti o sin di oloogbe ni odun 1953) je agbejoro, oloselu, ati agba-oje agbasaga omo Yoruba lati ilu Oyo lorile-ede Naijiria.[1] O pegede gege bi minisita nigba isejoba awon oyinbo ti n sakoso orile-ede Naijiria ki Naijiria to gba ominira lodun 1960. Oun kan naa ni Minisita igbokegbodo oko akoko lorile-ede Naijiria leyin ti Naijiria gba ominira.[2]

Awon Itokasi




Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads