Boyland–Sims oxidation

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Boyland–Sims oxidation jẹ́ ìdàpapọ̀ ṣiṣẹ́ kẹ́míkà ti àwọn aniline pẹ̀lú alkaline potassium persulfate, tí ó jẹ́ pé lẹ́yìn dídomi sí rẹ̀ ó maa di  ortho-hydroxyl àwọn aniline.[1][2][3]

Thumb
The Boyland-Sims oxidation

 Ortho-isomer ló maa ń jẹyọ. Síbẹ̀síbẹ̀, para-sulfate maa jẹyọ ní bíntí pẹ̀lú àwọn analine kan .[4]

Ètò ìdàpọ̀ ṣiṣẹ́

Behrman ti fihàn pé oun àkọ́kọ́ tí a maa rí nínú  Boyland–Sims oxidation ni jíjẹyọ arylhydroxylamine-O-sulfate (2).[5] Àtúntò zwitterionic yìí maa jẹ́ kí a rí ortho- sulfate (5), tí a maa domisí lati lè rí ortho-hydroxyl aniline.

Thumb
The mechanism of the Boyland-Sims oxidation

Ìwé àkàsíwájú si

Tún wo

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads