Elbs persulfate oxidation

From Wikipedia, the free encyclopedia

The Elbs persulfate oxidation jẹ́ ìdàpapọ̀ ṣiṣẹ́ ti àwọn phenol pẹ̀lú alkaline potassium persulfate lati di para-diphenols.[1]

Thumb
The Elbs persulfate oxidation

Oríṣíríṣi àwọn àgbéyẹ̀wò ní wọ́n ti tẹ̀jáde.[2][3][4]

Ètò ìdàpọ̀ ṣiṣẹ́

Wọ́n ti dába ètò ìdàpọ̀ ṣiṣẹ́ tí ó ṣàfihàn ìrọ́pò para nínú tautomeric para carbanion ti phenolate ion tí ó bẹ̀rẹ̀:[5] Ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú yíyọ nucleophile kúrò nínú peroxide oxygen ti peroxodisulfate (peroxydisulfate) ion, lati rí ẹgbẹ́ sulfate (3), tí wọ́n maa pomipọ̀ mọ́ sí ẹgbẹ́ hydroxyl.

Àìlánfàní tí ó rọ̀ mọ́ọ ní kẹ́míkà kékeré pẹ̀lú ohun ìdá àkọ́kọ́ àti èyí tí a lò pátápátá ti persulfate. Wọ́n dáa lábá pé  phenol lọ́pọ̀lọ́pọ̀ ọ̀nà jẹ́ amúlọsíwájú bá sísọ persulfate di sulfate.

Thumb
The Elbs persulfate oxidation

Tún wo

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.