Calvin Coolidge

Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Calvin Coolidge (John Calvin Coolidge Jr.;[1] /ˈkl/; tí a bí ní ọjọ́ kẹrin oṣù keje ọdún 1872 àti tí ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ Kàrún oṣù Kínní ọdún 1933) jẹ́ jẹ́ agbejọ́rò àti olọ́sẹ̀lú ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Òun ní Ààrẹ Ọgbọ́n láti gun orí àléfà Amerika, ó jé Ààrẹ láti ọdún 1923 di 1929.

Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads