Chanda Rubin

From Wikipedia, the free encyclopedia

Chanda Rubin
Remove ads

Chanda Rubin (ojoibi February 18, 1976) je agba tenis ara Amerika to ti feyinti. O gba ife-eye awon idije WTA Tour enikan meje, ipo re to gajulo ni World No. 6 ni April 8, 1996, leyin igba to de ilajidopin ni Open Australia 1996. Bakanna Rubin de ipo World No. 9 ninu idije enimeji, o gba Open Australia 1996 pelu Arantxa Sánchez Vicario.

Quick Facts Orílẹ̀-èdè, Ibùgbé ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads