Open Amẹ́ríkà

From Wikipedia, the free encyclopedia

Open Amẹ́ríkà
Remove ads

Ìdíje Open Tẹ́nìs Amẹ́ríkà tabi United States Open Tennis Championships, bakanna bi US Open, Open Amerika tabi Flushing Meadows, je idije tenis ori papa lile to je atunse odeoni ikan ninu awon idije tenis to pe julo lagbaye, eyun U.S. National Championship (Idije Omoorile-ede Amerika) ti fun awon okunrin enikan bere ni 1881.

Thumb
Open America(US) ti ọdún 2019

Quick facts Official website, Grand Slam ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads