Chinko Ekun
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Oladipo Olamide Emmanuel (tí wọ́n bí ní 13 September 1993), tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ sì jẹ́ Chinko Ekun, jẹ́ olórin àti akọrin sílẹ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè látiObafemi Awolowo University.
Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads
