Chris Brown

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia

Chris Brown
Remove ads

Christopher Maurice "Chris" Brown (ojoibi May 5, 1989) je olorin, onijo, ati osere ara Amerika. A bi ni Tappahannock, Virginia, o seko ara re lati mo orin ko ati ijo nigba to wa lomode be sini o tun je omo egbe akorin soosi. Ni gba to se adehun pelu Jive Records ni 2004, Brown gbe awo akoko to ni akole oruko re jade lodun to tele. O de ipo keji lori Billboard 200 ni Amerika be sini o gba iwe-eleri platinomu eleemeji latowo Recording Industry Association of America (RIAA) laipe. Pelu orin single akoko "Run It!" to de ipo kini lori Billboard Hot 100 ni Amerika, Brown di okunrin olorin akoko leyin Diddy ni 1997 to gbe awo jade nipo kinni lori chart Amerika. Awo re keji Exclusive (2007) na tun gbe orin single ipo kinni jade "Kiss Kiss", ati "With You" ati "Forever". Awo yi na gba iwe-eleri platinomu eleemeji latowo RIAA.

Quick facts Background information, Orúkọ àbísọ ...



Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads