Sean Combs

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia

Sean Combs
Remove ads

Sean John Combs (ojoibi November 4, 1969),[5] to tun gbajumo pelu awon oruko itage re Puff Daddy, Puffy, P. Diddy, ati Diddy, je olorin rap, akorin, akowe-orin, osere, akotun awo-orin ati onisowo ara Amerika. Won bi ni Harlem, o si dagba ni Mount Vernon, New York. O sise bi oludari talenti ni Uptown Records ko to da ile-ise ti e Bad Boy Entertainment sile ni 1993. Awo orin re akoko No Way Out (1997) ti gba iwe eri platinomu meje.

Quick facts Ọjọ́ìbí, Orúkọ míràn ...

Combs ti gba Ebun Grammy meta ati MTV Video Music Award meji, ohun si ni atokun eto telifisan MTV Making the Band. Ni 2017 Forbes so pe ola re to $820 million.[3]


Remove ads

Itokasi

Sources

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads