Chris Ngige
Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Àdàkọ:Infobox GovernorĦ Christian Nwabueze Ngige (bíi ní Ọjọ́ kẹjọ Oṣù kẹjọ Ọdún 1952) jẹ́ gómìnà Ipinle Anambra, Nàìjíríà láti Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Odún 2003 di Ọjọ́ kẹtàdínlógún Oṣù kẹta Odún 2006 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1] Wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àárín Anambra ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà ní Oṣù kẹrin Ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, APC.[2]
Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads