Kúbà tabi Orile-ede Olominira ile Kuba (pípè /ˈkjuːbə/ (
listen); Spánì: [República de Cuba] error: {{lang}}: text has italic markup (help), pronounced [reˈpuβlika ðe ˈkuβa] (
listen)) je orile-ede erekusu ni Karibeani. Orile-ede Kuba ni erekusu Kuba gbangba, Isla de la Juventud, ati awon sisupapo-erekusu.
Quick facts Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ KúbàRepublic of Cuba [República de Cuba] error: {{lang}}: text has italic markup (help) (Híspánì), Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ ...
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kúbà Republic of Cuba
[República de Cuba] error: {{lang}}: text has italic markup (help) (Híspánì)
|
|---|
|
Motto: Patria o Muerte (Híspánì) "Homeland or Death"[1] |
|
 |
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ | Havana |
|---|
| Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Spani |
|---|
| Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | 65.05% ènìyàn Funfun (Spani, àwọn yìókù), 10.08% ọmọ Afrika, 23.84% Mulatto ati Mestizo[3] |
|---|
| Orúkọ aráàlú | Cuban |
|---|
| Ìjọba | Orílẹ̀-èdè sósíálístì àwọn òsìṣẹ́, gbígbájọ bíi orílẹ̀-èdè olómìnira aparapọ̀ àti tòṣèlúaráìlú[4] Orílẹ̀-èdè kómúnístì[5] |
|---|
|
• Ààrẹ | Miguel Díaz-Canel |
|---|
• Igbákejì Ààrẹ̀ Àkọ́kọ́ | Salvador Valdés Mesa |
|---|
| Raúl Castro |
|---|
|
|
| Ìlómìnira kúrò lọ́dọ̀ Spein |
|---|
|
• Fífilọ́lẹ̀ | 10 Oṣù Kẹ̀wá, 1868 |
|---|
• Fífilọ́lẹ̀ bíi olómìnira | 20 Oṣù Kárún, 1902 kúrò lódò U.S |
|---|
• Ìjídìde Kúbà | 1 Osú Kínní, 1959 |
|---|
|
|
| Ìtóbi |
|---|
• Total | 109,886 km2 (42,427 sq mi) (105th) |
|---|
• Omi (%) | negligible[6] |
|---|
| Alábùgbé |
|---|
• 2008 estimate | 11,236,444[7] (75th) |
|---|
• 2002 census | 11,177,743[7] |
|---|
• Ìdìmọ́ra | 102/km2 (264.2/sq mi) (97th) |
|---|
| GDP (PPP) | 2009 estimate |
|---|
• Total | $111.1 billion[8] (62nd) |
|---|
• Per capita | $9,700 (86th) |
|---|
| GDP (nominal) | 2008 estimate |
|---|
• Total | $65.67 billion[9] (63rd) |
|---|
• Per capita | $5,844 (80th) |
|---|
| HDI (2007) | 0.863[10] Error: Invalid HDI value · 51st |
|---|
| Owóníná | Pẹ́só Kúbà(CUP) Cuban convertible peso[11] (CUC) |
|---|
| Ibi àkókò | UTC-5 |
|---|
• Ìgbà oru (DST) | UTC-4 ((March 11 to November 4)) |
|---|
| Ojúọ̀nà ọkọ́ | ọ̀tún |
|---|
| Àmì tẹlifóònù | +53 |
|---|
| Internet TLD | .cu |
|---|
Close
Havana ni ilu titobijulo nibe ati oluilu re. Santiago de Cuba ni ilu keji totobijulo.[12][13]