Daniella Okeke
Òṣéré orí ìtàgé From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Daniella Okeke jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ní ọdún 2013, ó kó ipa "Jọké" nínu eré Lagos Cougars, ipa kan tí ó fun lánfàní yíyàn fún ti òṣère tí ó dára jùlọ ní ipa asíwájú níbi ìkéde ẹ̀lẹ́kẹẹ̀wá ti African Movie Academy Awards àti Nigeria Entertainment Awards ti ọdún 2014.[1][2][3][4][5]
Remove ads
Ìgbé ayé rẹ̀
Okeke ni a bí ní Oṣù Kẹẹ̀ta Ọjọ́ 26, Ọdún 1987. Ó wá láti Ìpínlẹ̀ Ímò.[6] Okeke jẹ́ ẹnìkan tí ó fẹ́ràn àwọn ọkọ̀ bọ̀gìnì.[7]
Àṣàyàn eré rẹ̀
- Sleek Ladies (2007)
- Stronger than Pain (2007)
- Lagos Cougars
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads