Debbie Allen

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia

Debbie Allen
Remove ads

Deborah Kaye Allen (ojoibi January 16, 1950) to gbajumo lasan bi Debbie Allen je osere, onijo, oluko-ijo, akorin-akowe-orin, oludari, olootu ara Amerika, ati omo egbe tele President's Committee on the Arts and Humanities.[1][2] Won ti pe loruko ni igba ogun fun Ebun Emmy (o gba ni emeta),[3] igba emeji fun Ebun Tony,[4] be ni o si gba Ebun Golden Globe ni ekan,[5] won si fun ni irawo ni ori Hollywood Walk of Fame ni 1991.

Quick facts Ọjọ́ìbí, Orílẹ̀-èdè ...

Allen gbajumo fun ere re lori ere orin-dirama telifisan Fame (1982-1987), nibi to ti sere bi Lydia Grant, olukoni-nijo, ohun si lo se oluko-ijo agba fun ere telifisan na. Fun isere yi ni 1983 o gba Ebun Golden Globe and Ebun Tony meji won si peloruko fun Ebun Emmy merin. Leyin na Allen sise bi oludari ati olootu, nibi to ti se olootu ati oludari ere osoose 83 ninu 144 fun ere komedi NBC A Different World (1988-1993). O pada si nisere ngba to kopa ninu ere telifisan NBC In the House lati 1995 di 1996, ati lati 2011 o bere sini sere bi Dr. Catherine Avery ninu ere dirama ile-iwosan ABC Grey's Anatomy nibi to tun ti sise bi olootu agba ati oludari.[6] O se oludari ere telifisan ati filmu to to 50.

Ni 2001, Allen si ile-eko ikojo Debbie Allen Dance Academy ni Los Angeles, California.[7][8] Ohun ni aburo Phylicia Rashad ti ohun na je akorin, osere ati oludari.


Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads